Lúùkù 21:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Torí gbogbo àwọn yìí fi ẹ̀bùn sílẹ̀ látinú àjẹṣẹ́kù wọn, àmọ́ òun, láìka pé kò ní lọ́wọ́,* ó fi gbogbo ohun tó ní láti gbé ẹ̀mí rẹ̀ ró síbẹ̀.”+
4 Torí gbogbo àwọn yìí fi ẹ̀bùn sílẹ̀ látinú àjẹṣẹ́kù wọn, àmọ́ òun, láìka pé kò ní lọ́wọ́,* ó fi gbogbo ohun tó ní láti gbé ẹ̀mí rẹ̀ ró síbẹ̀.”+