18 Àmọ́ mo béèrè pé, Ṣé wọn ò gbọ́ ni? Wọ́n kúkú gbọ́. Torí, ní tòótọ́, “ohùn wọn ti dún jáde lọ sí gbogbo ayé, iṣẹ́ tí wọ́n ń jẹ́ sì ti dé ìkángun ilẹ̀ ayé tí à ń gbé.”+
6 Mo rí áńgẹ́lì míì tó ń fò lójú ọ̀run,* ó ní ìhìn rere àìnípẹ̀kun láti kéde fún àwọn tó ń gbé ayé, fún gbogbo orílẹ̀-èdè àti ẹ̀yà àti ahọ́n* àti èèyàn.+