ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Míkà 7:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Torí ọmọkùnrin ń tàbùkù sí bàbá rẹ̀,

      Ọmọbìnrin ń bá ìyá rẹ̀ jà,+

      Ìyàwó ń gbógun ti ìyá ọkọ rẹ̀;+

      Ará ilé ẹni ni ọ̀tá ẹni.+

  • Mátíù 10:21
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 21 Bákan náà, arákùnrin máa fa arákùnrin lé ikú lọ́wọ́, bàbá máa ṣe bẹ́ẹ̀ sí ọmọ rẹ̀, àwọn ọmọ máa dìde sí àwọn òbí, wọ́n sì máa pa wọ́n.+

  • Lúùkù 21:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Bákan náà, àwọn òbí, àwọn arákùnrin, àwọn mọ̀lẹ́bí àti àwọn ọ̀rẹ́ pàápàá máa fà yín léni lọ́wọ́,* wọ́n máa pa àwọn kan nínú yín,+

  • 2 Tímótì 3:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Àmọ́ kí o mọ èyí pé, àwọn ọjọ́ ìkẹyìn+ yóò jẹ́ àkókò tí nǹkan máa le gan-an, tó sì máa nira.

  • 2 Tímótì 3:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 ẹni tí kò ní ìfẹ́ àdámọ́ni, kìígbọ́-kìígbà,* abanijẹ́, ẹni tí kò lè kó ara rẹ̀ níjàánu, ẹni tó burú gan-an, ẹni tí kò nífẹ̀ẹ́ ohun rere,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́