2 Tímótì 4:7 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 7 Mo ti ja ìjà rere náà,+ mo ti sá eré ìje náà dé ìparí,+ mo ti pa ìgbàgbọ́ mọ́. Hébérù 3:6 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 6 àmọ́ Kristi jẹ́ olóòótọ́ ọmọ+ lórí ilé Ọlọ́run. Àwa ni ilé Rẹ̀,+ tí a bá rí i dájú pé a ò jẹ́ kí ohunkóhun dí wa lọ́wọ́ láti máa sọ̀rọ̀ ní fàlàlà, tí a sì di ìrètí tí a fi ń yangàn mú ṣinṣin títí dé òpin.
6 àmọ́ Kristi jẹ́ olóòótọ́ ọmọ+ lórí ilé Ọlọ́run. Àwa ni ilé Rẹ̀,+ tí a bá rí i dájú pé a ò jẹ́ kí ohunkóhun dí wa lọ́wọ́ láti máa sọ̀rọ̀ ní fàlàlà, tí a sì di ìrètí tí a fi ń yangàn mú ṣinṣin títí dé òpin.