-
Mátíù 9:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Jésù mọ ohun tí wọ́n ń rò, ó wá sọ pé: “Kí ló dé tí ẹ̀ ń ro ohun burúkú nínú ọkàn yín?+
-
-
Lúùkù 6:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Àmọ́ ó mọ ohun tí wọ́n ń rò,+ torí náà, ó sọ fún ọkùnrin tí ọwọ́ rẹ̀ rọ náà pé: “Dìde, kí o dúró ní àárín.” Ó dìde, ó sì dúró síbẹ̀.
-