Lúùkù 21:36 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Torí náà, ẹ máa wà lójúfò,+ kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀ nígbà gbogbo,+ kí ẹ lè bọ́ nínú gbogbo nǹkan tó gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ yìí, kí ẹ sì lè dúró níwájú Ọmọ èèyàn.”+
36 Torí náà, ẹ máa wà lójúfò,+ kí ẹ máa rawọ́ ẹ̀bẹ̀ nígbà gbogbo,+ kí ẹ lè bọ́ nínú gbogbo nǹkan tó gbọ́dọ̀ ṣẹlẹ̀ yìí, kí ẹ sì lè dúró níwájú Ọmọ èèyàn.”+