Lúùkù 22:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Torí, ní tòótọ́, Ọmọ èèyàn ń bá ọ̀nà rẹ̀ lọ bí a ṣe pinnu rẹ̀; + síbẹ̀, ọkùnrin tí a tipasẹ̀ rẹ̀ fi í léni lọ́wọ́ gbé!”+
22 Torí, ní tòótọ́, Ọmọ èèyàn ń bá ọ̀nà rẹ̀ lọ bí a ṣe pinnu rẹ̀; + síbẹ̀, ọkùnrin tí a tipasẹ̀ rẹ̀ fi í léni lọ́wọ́ gbé!”+