Mátíù 26:27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 27 Ó mú ife kan, ó dúpẹ́, ó sì gbé e fún wọn, ó ní: “Gbogbo yín, ẹ mu nínú rẹ̀,+ 1 Kọ́ríńtì 10:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ife ìbùkún tí a súre sí, ṣebí láti pín nínú ẹ̀jẹ̀ Kristi ni?+ Ìṣù búrẹ́dì tí a bù, ṣebí láti pín nínú ara Kristi ni?+ 1 Kọ́ríńtì 11:25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 25 Ó ṣe bákan náà ní ti ife náà,+ lẹ́yìn tí wọ́n ti jẹ oúnjẹ alẹ́, ó ní: “Ife yìí túmọ̀ sí májẹ̀mú tuntun+ tí a fi ẹ̀jẹ̀ mi dá.*+ Nígbàkigbà tí ẹ bá ń mu ún, ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”+
16 Ife ìbùkún tí a súre sí, ṣebí láti pín nínú ẹ̀jẹ̀ Kristi ni?+ Ìṣù búrẹ́dì tí a bù, ṣebí láti pín nínú ara Kristi ni?+
25 Ó ṣe bákan náà ní ti ife náà,+ lẹ́yìn tí wọ́n ti jẹ oúnjẹ alẹ́, ó ní: “Ife yìí túmọ̀ sí májẹ̀mú tuntun+ tí a fi ẹ̀jẹ̀ mi dá.*+ Nígbàkigbà tí ẹ bá ń mu ún, ẹ máa ṣe èyí ní ìrántí mi.”+