Mátíù 26:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Níkẹyìn, lẹ́yìn tí wọ́n kọrin ìyìn,* wọ́n lọ sí Òkè Ólífì.+ Lúùkù 22:39 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Nígbà tó kúrò níbẹ̀, ó lọ sí Òkè Ólífì bó ṣe máa ń ṣe, àwọn ọmọ ẹ̀yìn náà sì tẹ̀ lé e.+ Jòhánù 18:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 18 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, Jésù àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí òdìkejì Àfonífojì Kídírónì,*+ níbi tí ọgbà kan wà, òun àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sì wọnú ibẹ̀.+
18 Lẹ́yìn tó sọ àwọn nǹkan yìí, Jésù àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí òdìkejì Àfonífojì Kídírónì,*+ níbi tí ọgbà kan wà, òun àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sì wọnú ibẹ̀.+