Mátíù 26:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ẹ̀dùn ọkàn bá mi* gan-an, àní títí dé ikú. Ẹ dúró síbí, kí ẹ sì máa ṣọ́nà pẹ̀lú mi.”+
38 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ẹ̀dùn ọkàn bá mi* gan-an, àní títí dé ikú. Ẹ dúró síbí, kí ẹ sì máa ṣọ́nà pẹ̀lú mi.”+