Mátíù 26:41 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 41 Ẹ máa ṣọ́nà,+ kí ẹ sì máa gbàdúrà nígbà gbogbo,+ kí ẹ má bàa kó sínú ìdẹwò.+ Ní tòótọ́, ẹ̀mí ń fẹ́,* àmọ́ ẹran ara jẹ́ aláìlera.”+ Róòmù 7:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 àmọ́ mo rí òfin míì nínú ara* mi+ tó ń bá òfin tó ń darí èrò mi jagun, tó sì ń sọ mí di ẹrú òfin ẹ̀ṣẹ̀+ tó wà nínú ara* mi.
41 Ẹ máa ṣọ́nà,+ kí ẹ sì máa gbàdúrà nígbà gbogbo,+ kí ẹ má bàa kó sínú ìdẹwò.+ Ní tòótọ́, ẹ̀mí ń fẹ́,* àmọ́ ẹran ara jẹ́ aláìlera.”+
23 àmọ́ mo rí òfin míì nínú ara* mi+ tó ń bá òfin tó ń darí èrò mi jagun, tó sì ń sọ mí di ẹrú òfin ẹ̀ṣẹ̀+ tó wà nínú ara* mi.