-
Jòhánù 18:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Jésù dá a lóhùn pé: “Mo ti bá ayé sọ̀rọ̀ ní gbangba. Gbogbo ìgbà ni mò ń kọ́ni nínú sínágọ́gù àti nínú tẹ́ńpìlì,+ níbi tí gbogbo àwọn Júù ń kóra jọ sí; mi ò sì sọ ohunkóhun ní ìkọ̀kọ̀.
-