Jòhánù 18:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Wọ́n kọ́kọ́ mú un lọ sọ́dọ̀ Ánásì, torí òun ni bàbá ìyàwó Káyáfà,+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ́dún yẹn.+
13 Wọ́n kọ́kọ́ mú un lọ sọ́dọ̀ Ánásì, torí òun ni bàbá ìyàwó Káyáfà,+ tó jẹ́ àlùfáà àgbà lọ́dún yẹn.+