Lúùkù 22:63-65 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 63 Àwọn ọkùnrin tó mú Jésù wá bẹ̀rẹ̀ sí í fi Jésù ṣe yẹ̀yẹ́,+ wọ́n ń lù ú;+ 64 lẹ́yìn tí wọ́n sì fi nǹkan bò ó lójú, wọ́n ń bi í pé: “Sọ tẹ́lẹ̀! Ta lẹni tó gbá ọ?” 65 Wọ́n sì sọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀rọ̀ òdì míì sí i.
63 Àwọn ọkùnrin tó mú Jésù wá bẹ̀rẹ̀ sí í fi Jésù ṣe yẹ̀yẹ́,+ wọ́n ń lù ú;+ 64 lẹ́yìn tí wọ́n sì fi nǹkan bò ó lójú, wọ́n ń bi í pé: “Sọ tẹ́lẹ̀! Ta lẹni tó gbá ọ?” 65 Wọ́n sì sọ ọ̀pọ̀lọpọ̀ ọ̀rọ̀ òdì míì sí i.