Jòhánù 18:33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 33 Torí náà, Pílátù tún wọnú ilé gómìnà, ó pe Jésù, ó sì bi í pé: “Ṣé ìwọ ni Ọba Àwọn Júù?”+ Jòhánù 18:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 Pílátù wá bi í pé: “Ó dáa, ṣé ọba ni ọ́?” Jésù dáhùn pé: “Ìwọ fúnra rẹ ń sọ pé ọba ni mí.+ Torí èyí la ṣe bí mi, torí èyí sì ni mo ṣe wá sí ayé, kí n lè jẹ́rìí sí òtítọ́.+ Gbogbo ẹni tó bá fara mọ́ òtítọ́ ń fetí sí ohùn mi.”
37 Pílátù wá bi í pé: “Ó dáa, ṣé ọba ni ọ́?” Jésù dáhùn pé: “Ìwọ fúnra rẹ ń sọ pé ọba ni mí.+ Torí èyí la ṣe bí mi, torí èyí sì ni mo ṣe wá sí ayé, kí n lè jẹ́rìí sí òtítọ́.+ Gbogbo ẹni tó bá fara mọ́ òtítọ́ ń fetí sí ohùn mi.”