Jòhánù 19:9, 10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 ló bá tún wọ ilé gómìnà, ó sì sọ fún Jésù pé: “Ibo lo ti wá?” Àmọ́ Jésù ò dá a lóhùn.+ 10 Torí náà, Pílátù sọ fún un pé: “Ṣé o ò fẹ́ bá mi sọ̀rọ̀ ni? Àbí o ò mọ̀ pé mo ní àṣẹ láti tú ọ sílẹ̀, mo sì tún ní àṣẹ láti pa ọ́?”*
9 ló bá tún wọ ilé gómìnà, ó sì sọ fún Jésù pé: “Ibo lo ti wá?” Àmọ́ Jésù ò dá a lóhùn.+ 10 Torí náà, Pílátù sọ fún un pé: “Ṣé o ò fẹ́ bá mi sọ̀rọ̀ ni? Àbí o ò mọ̀ pé mo ní àṣẹ láti tú ọ sílẹ̀, mo sì tún ní àṣẹ láti pa ọ́?”*