ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 27:32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 32 Bí wọ́n ṣe ń jáde lọ, wọ́n rí ọkùnrin ará Kírénè kan tó ń jẹ́ Símónì. Wọ́n fi dandan mú ọkùnrin yìí pé kó gbé òpó igi oró* rẹ̀.+

  • Lúùkù 23:26
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 26 Bí wọ́n ṣe ń mú un lọ, wọ́n mú ẹnì kan, ìyẹn Símónì ará Kírénè, ó ń bọ̀ láti ìgbèríko, wọ́n sì gbé òpó igi oró* náà lé e pé kó gbé e tẹ̀ lé Jésù.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́