-
Mátíù 27:29Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
29 wọ́n wá fi ẹ̀gún hun adé, wọ́n dé e sí i lórí, wọ́n sì fi ọ̀pá esùsú sí ọwọ́ ọ̀tún rẹ̀. Wọ́n wá kúnlẹ̀ síwájú rẹ̀, wọ́n sì ń fi ṣe yẹ̀yẹ́, wọ́n ń sọ pé: “A kí ọ o,* ìwọ Ọba Àwọn Júù!”
-
-
Mátíù 27:37Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
37 Wọ́n tún gbé àkọlé sókè orí rẹ̀, tí wọ́n kọ ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn án sí, pé: “Jésù Ọba Àwọn Júù nìyí.”+
-
-
Lúùkù 23:38Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
38 Àkọlé kan tún wà lórí rẹ̀ pé: “Ọba Àwọn Júù nìyí.”+
-