Mátíù 16:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Ìran burúkú àti alágbèrè* kò yéé wá àmì, àmọ́ a ò ní fún un ní àmì kankan+ àfi àmì Jónà.”+ Ló bá kúrò níbẹ̀, ó sì fi wọ́n sílẹ̀.
4 Ìran burúkú àti alágbèrè* kò yéé wá àmì, àmọ́ a ò ní fún un ní àmì kankan+ àfi àmì Jónà.”+ Ló bá kúrò níbẹ̀, ó sì fi wọ́n sílẹ̀.