Ẹ́kísódù 20:8, 9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 “Máa rántí ọjọ́ Sábáàtì, kí o lè yà á sí mímọ́.+ 9 Ọjọ́ mẹ́fà ni kí o fi ṣiṣẹ́, kí o sì fi ṣe gbogbo iṣẹ́ rẹ,+
8 “Máa rántí ọjọ́ Sábáàtì, kí o lè yà á sí mímọ́.+ 9 Ọjọ́ mẹ́fà ni kí o fi ṣiṣẹ́, kí o sì fi ṣe gbogbo iṣẹ́ rẹ,+