Lúùkù 23:55, 56 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Àmọ́ àwọn obìnrin tó bá a wá láti Gálílì tẹ̀ lé e lọ, wọ́n yọjú wo ibojì* náà, wọ́n sì rí i bí wọ́n ṣe tẹ́ òkú rẹ̀,+ 56 wọ́n wá pa dà lọ pèsè èròjà tó ń ta sánsán àti àwọn òróró onílọ́fínńdà. Àmọ́ wọ́n sinmi ní Sábáàtì+ bí a ṣe pa á láṣẹ.
55 Àmọ́ àwọn obìnrin tó bá a wá láti Gálílì tẹ̀ lé e lọ, wọ́n yọjú wo ibojì* náà, wọ́n sì rí i bí wọ́n ṣe tẹ́ òkú rẹ̀,+ 56 wọ́n wá pa dà lọ pèsè èròjà tó ń ta sánsán àti àwọn òróró onílọ́fínńdà. Àmọ́ wọ́n sinmi ní Sábáàtì+ bí a ṣe pa á láṣẹ.