Jòhánù 12:39, 40 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 39 Ìdí tí wọn ò fi gbà gbọ́ ni pé Àìsáyà tún sọ pé: 40 “Ó ti fọ́ ojú wọn, ó sì ti mú kí ọkàn wọn le, kí wọ́n má bàa fi ojú wọn ríran, kí ọkàn wọn má sì lóye, kí wọ́n lè yí pa dà, kí n sì mú wọn lára dá.”+
39 Ìdí tí wọn ò fi gbà gbọ́ ni pé Àìsáyà tún sọ pé: 40 “Ó ti fọ́ ojú wọn, ó sì ti mú kí ọkàn wọn le, kí wọ́n má bàa fi ojú wọn ríran, kí ọkàn wọn má sì lóye, kí wọ́n lè yí pa dà, kí n sì mú wọn lára dá.”+