Lúùkù 6:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Nígbà yẹn, ó lọ sórí òkè lọ́jọ́ kan láti gbàdúrà,+ ó sì fi gbogbo òru gbàdúrà sí Ọlọ́run.+ 13 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, ó pe àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sọ́dọ̀, ó sì yan méjìlá (12) lára wọn, ó tún pè wọ́n ní àpọ́sítélì,+ àwọn ni:
12 Nígbà yẹn, ó lọ sórí òkè lọ́jọ́ kan láti gbàdúrà,+ ó sì fi gbogbo òru gbàdúrà sí Ọlọ́run.+ 13 Nígbà tí ilẹ̀ mọ́, ó pe àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ sọ́dọ̀, ó sì yan méjìlá (12) lára wọn, ó tún pè wọ́n ní àpọ́sítélì,+ àwọn ni: