-
Lúùkù 11:17, 18Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
17 Ó mọ ohun tí wọ́n ń rò,+ ó wá sọ fún wọn pé: “Gbogbo ìjọba tó bá pínyà sí ara rẹ̀ máa pa run, ilé tó bá sì pínyà sí ara rẹ̀ máa wó. 18 Lọ́nà kan náà, tí Sátánì náà bá pínyà sí ara rẹ̀, báwo ni ìjọba rẹ̀ ṣe máa dúró? Torí ẹ sọ pé Béélísébúbù ni mo fi ń lé àwọn ẹ̀mí èṣù jáde.
-