Mátíù 3:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Lẹ́yìn náà, Jésù wá láti Gálílì sí Jọ́dánì, ó wá sọ́dọ̀ Jòhánù kó lè ṣèrìbọmi fún òun.+ Lúùkù 3:21, 22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Nígbà tí gbogbo àwọn èèyàn náà ṣèrìbọmi, Jésù náà ṣèrìbọmi.+ Bó ṣe ń gbàdúrà, ọ̀run ṣí sílẹ̀,+ 22 ẹ̀mí mímọ́ bà lé e, ẹ̀mí náà rí bí àdàbà, ohùn kan sì dún láti ọ̀run pé: “Ìwọ ni Ọmọ mi, àyànfẹ́; mo ti tẹ́wọ́ gbà ọ́.”+
21 Nígbà tí gbogbo àwọn èèyàn náà ṣèrìbọmi, Jésù náà ṣèrìbọmi.+ Bó ṣe ń gbàdúrà, ọ̀run ṣí sílẹ̀,+ 22 ẹ̀mí mímọ́ bà lé e, ẹ̀mí náà rí bí àdàbà, ohùn kan sì dún láti ọ̀run pé: “Ìwọ ni Ọmọ mi, àyànfẹ́; mo ti tẹ́wọ́ gbà ọ́.”+