ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 12:31, 32
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 31 “Nítorí èyí, mò ń sọ fún yín pé, gbogbo oríṣiríṣi ẹ̀ṣẹ̀ àti ọ̀rọ̀ òdì la máa dárí rẹ̀ ji àwọn èèyàn, àmọ́ ọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí kò ní ìdáríjì.+ 32 Bí àpẹẹrẹ, ẹnikẹ́ni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí Ọmọ èèyàn máa rí ìdáríjì;+ àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́, kò ní rí ìdáríjì, àní, nínú ètò àwọn nǹkan yìí* tàbí èyí tó ń bọ̀.+

  • Lúùkù 12:10
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Gbogbo ẹni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí Ọmọ èèyàn, a máa dárí rẹ̀ jì í, àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá sọ̀rọ̀ òdì sí ẹ̀mí mímọ́ kò ní rí ìdáríjì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́