-
Jòhánù 7:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àwọn èèyàn dáhùn pé: “Ẹlẹ́mìí èṣù ni ọ́. Ta ló fẹ́ pa ọ́?”
-
-
Jòhánù 10:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Ọ̀pọ̀ nínú wọn ń sọ pé: “Ẹlẹ́mìí èṣù ni, orí rẹ̀ sì ti yí. Kí ló dé tí ẹ̀ ń fetí sí i?”
-