Mátíù 13:55 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 55 Àbí ọmọ káfíńtà kọ́ nìyí?+ Ṣebí Màríà lorúkọ ìyá rẹ̀, Jémíìsì, Jósẹ́fù, Símónì àti Júdásì sì ni àwọn arákùnrin rẹ̀?+ Jòhánù 2:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Lẹ́yìn náà, òun, ìyá rẹ̀, àwọn arákùnrin rẹ̀+ àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí Kápánáúmù,+ àmọ́ wọn ò pẹ́ níbẹ̀. Ìṣe 1:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Gbogbo wọn tẹra mọ́ àdúrà pẹ̀lú èrò tó ṣọ̀kan, àwọn àti àwọn obìnrin kan+ pẹ̀lú Màríà ìyá Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀.+
55 Àbí ọmọ káfíńtà kọ́ nìyí?+ Ṣebí Màríà lorúkọ ìyá rẹ̀, Jémíìsì, Jósẹ́fù, Símónì àti Júdásì sì ni àwọn arákùnrin rẹ̀?+
12 Lẹ́yìn náà, òun, ìyá rẹ̀, àwọn arákùnrin rẹ̀+ àti àwọn ọmọ ẹ̀yìn rẹ̀ lọ sí Kápánáúmù,+ àmọ́ wọn ò pẹ́ níbẹ̀.
14 Gbogbo wọn tẹra mọ́ àdúrà pẹ̀lú èrò tó ṣọ̀kan, àwọn àti àwọn obìnrin kan+ pẹ̀lú Màríà ìyá Jésù àti àwọn arákùnrin rẹ̀.+