Mátíù 12:50 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 50 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń ṣe ìfẹ́ Baba mi tó wà ní ọ̀run, ẹni yẹn ni arákùnrin mi, arábìnrin mi àti ìyá mi.”+ Lúùkù 8:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Ó dá wọn lóhùn pé: “Ìyá mi àti àwọn arákùnrin mi ni àwọn yìí tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí wọ́n sì ń ṣe é.”+ Jòhánù 15:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Ọ̀rẹ́ mi ni yín, tí ẹ bá ń ṣe ohun tí mò ń pa láṣẹ fún yín.+
50 Torí ẹnikẹ́ni tó bá ń ṣe ìfẹ́ Baba mi tó wà ní ọ̀run, ẹni yẹn ni arákùnrin mi, arábìnrin mi àti ìyá mi.”+
21 Ó dá wọn lóhùn pé: “Ìyá mi àti àwọn arákùnrin mi ni àwọn yìí tó ń gbọ́ ọ̀rọ̀ Ọlọ́run, tí wọ́n sì ń ṣe é.”+