ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jòhánù 15:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 kí ẹ̀yin náà sì jẹ́rìí,+ torí pé ẹ ti wà pẹ̀lú mi láti ìbẹ̀rẹ̀.

  • 1 Pétérù 5:1
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 5 Torí náà, bí èmi náà ti jẹ́ alàgbà, tí mo fojú ara mi rí àwọn ìyà tí Kristi jẹ, tí mo sì máa pín nínú ògo tí a máa ṣí payá,+ mò ń rọ àwọn alàgbà tó wà láàárín yín* pé:

  • 2 Pétérù 1:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Ó dájú pé kì í ṣe àwọn ìtàn èké tí a dọ́gbọ́n hùmọ̀ la tẹ̀ lé nígbà tí a jẹ́ kí ẹ mọ agbára Olúwa wa Jésù Kristi àti ìgbà tó máa wà níhìn-ín, àmọ́ a fi ojú ara wa rí ọlá ńlá rẹ̀.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́