Jòhánù 1:26, 27 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 26 Jòhánù dá wọn lóhùn pé: “Omi ni mo fi ń batisí. Ẹnì kan wà láàárín yín tí ẹ kò mọ̀, 27 ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi, ẹni tí mi ò tó tú okùn bàtà rẹ̀.”+
26 Jòhánù dá wọn lóhùn pé: “Omi ni mo fi ń batisí. Ẹnì kan wà láàárín yín tí ẹ kò mọ̀, 27 ẹni tó ń bọ̀ lẹ́yìn mi, ẹni tí mi ò tó tú okùn bàtà rẹ̀.”+