Lúùkù 7:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Mò ń sọ fún yín, nínú àwọn tí obìnrin bí, kò sí ẹni tó tóbi ju Jòhánù lọ, àmọ́ ẹni kékeré nínú Ìjọba Ọlọ́run tóbi jù ú lọ.”+
28 Mò ń sọ fún yín, nínú àwọn tí obìnrin bí, kò sí ẹni tó tóbi ju Jòhánù lọ, àmọ́ ẹni kékeré nínú Ìjọba Ọlọ́run tóbi jù ú lọ.”+