Lúùkù 2:34 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 34 Bákan náà, Síméónì súre fún wọn, ó sì sọ fún Màríà, ìyá ọmọ náà pé: “Wò ó! A ti yan ọmọ yìí kí ọ̀pọ̀ ní Ísírẹ́lì lè ṣubú,+ kí ọ̀pọ̀ sì tún dìde,+ kó sì lè jẹ́ àmì tí wọ́n máa sọ̀rọ̀ lòdì sí +
34 Bákan náà, Síméónì súre fún wọn, ó sì sọ fún Màríà, ìyá ọmọ náà pé: “Wò ó! A ti yan ọmọ yìí kí ọ̀pọ̀ ní Ísírẹ́lì lè ṣubú,+ kí ọ̀pọ̀ sì tún dìde,+ kó sì lè jẹ́ àmì tí wọ́n máa sọ̀rọ̀ lòdì sí +