Hébérù 2:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 báwo la ṣe máa bọ́ tí a ò bá ka irú ìgbàlà tó tóbi bẹ́ẹ̀ sí? + Torí Olúwa wa bẹ̀rẹ̀ sí í sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀,+ àwọn tó gbọ́ ọ lẹ́nu rẹ̀ sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ fún wa,
3 báwo la ṣe máa bọ́ tí a ò bá ka irú ìgbàlà tó tóbi bẹ́ẹ̀ sí? + Torí Olúwa wa bẹ̀rẹ̀ sí í sọ̀rọ̀ nípa rẹ̀,+ àwọn tó gbọ́ ọ lẹ́nu rẹ̀ sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ fún wa,