Mátíù 8:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Nígbà tí Jésù gbọ́ ohun tó sọ, ó yà á lẹ́nu, ó sì sọ fún àwọn tó ń tẹ̀ lé e pé: “Kí n sọ òótọ́ fún yín, mi ò tíì rí ẹnì kankan ní Ísírẹ́lì tó ní ìgbàgbọ́ tó lágbára tó báyìí.+
10 Nígbà tí Jésù gbọ́ ohun tó sọ, ó yà á lẹ́nu, ó sì sọ fún àwọn tó ń tẹ̀ lé e pé: “Kí n sọ òótọ́ fún yín, mi ò tíì rí ẹnì kankan ní Ísírẹ́lì tó ní ìgbàgbọ́ tó lágbára tó báyìí.+