Àìsáyà 7:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Torí náà, Jèhófà fúnra rẹ̀ máa fún yín ní àmì kan: Wò ó! Ọ̀dọ́bìnrin náà* máa lóyún, ó sì máa bí ọmọkùnrin kan,+ ó máa pe orúkọ rẹ̀ ní Ìmánúẹ́lì.*+ Mátíù 1:24, 25 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Jósẹ́fù wá jí lójú oorun, ó sì ṣe ohun tí áńgẹ́lì Jèhófà* ní kó ṣe, ó mú ìyàwó rẹ̀ lọ sílé. 25 Àmọ́ kò ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú rẹ̀ títí ó fi bí ọmọkùnrin kan,+ ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jésù.+
14 Torí náà, Jèhófà fúnra rẹ̀ máa fún yín ní àmì kan: Wò ó! Ọ̀dọ́bìnrin náà* máa lóyún, ó sì máa bí ọmọkùnrin kan,+ ó máa pe orúkọ rẹ̀ ní Ìmánúẹ́lì.*+
24 Jósẹ́fù wá jí lójú oorun, ó sì ṣe ohun tí áńgẹ́lì Jèhófà* ní kó ṣe, ó mú ìyàwó rẹ̀ lọ sílé. 25 Àmọ́ kò ní ìbálòpọ̀ pẹ̀lú rẹ̀ títí ó fi bí ọmọkùnrin kan,+ ó sì pe orúkọ rẹ̀ ní Jésù.+