ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 10:14
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 14 Ibikíbi tí ẹnikẹ́ni ò bá ti gbà yín tàbí fetí sí ọ̀rọ̀ yín, tí ẹ bá ń kúrò ní ilé yẹn tàbí ìlú yẹn, ẹ gbọn iyẹ̀pẹ̀ ẹsẹ̀ yín dà nù.+

  • Máàkù 6:11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 11 Níbikíbi tí wọn ò bá sì ti gbà yín tàbí fetí sí ọ̀rọ̀ yín, tí ẹ bá ń kúrò níbẹ̀, ẹ gbọn iyẹ̀pẹ̀ tó wà lábẹ́ ẹsẹ̀ yín dà nù, kó lè jẹ́ ẹ̀rí fún wọn.”+

  • Lúùkù 10:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 Àmọ́ ibikíbi tí ẹ bá ti wọ ìlú kan, tí wọn ò sì gbà yín, ẹ lọ sí àwọn ọ̀nà rẹ̀ tó bọ́ sí gbangba, kí ẹ sì sọ pé: 11 ‘A nu eruku tó lẹ̀ mọ́ wa lẹ́sẹ̀ pàápàá látinú ìlú yín kúrò lòdì sí yín.+ Síbẹ̀, ẹ fi èyí sọ́kàn pé Ìjọba Ọlọ́run ti sún mọ́lé.’

  • Ìṣe 13:50, 51
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 50 Àmọ́ àwọn Júù ru àwọn obìnrin olókìkí tó bẹ̀rù Ọlọ́run àti àwọn ọkùnrin sàràkí-sàràkí ìlú náà sókè, wọ́n gbé inúnibíni+ dìde sí Pọ́ọ̀lù àti Bánábà, wọ́n sì jù wọ́n sí ẹ̀yìn ààlà ìlú wọn. 51 Torí náà, wọ́n gbọn ekuru ẹsẹ̀ wọn dà nù sí wọn, wọ́n sì lọ sí Íkóníónì.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́