Róòmù 12:12 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Ẹ jẹ́ kí ìrètí tí ẹ ní máa fún yín láyọ̀. Ẹ máa fara da ìpọ́njú.+ Ẹ máa tẹra mọ́ àdúrà gbígbà.+