-
Lúùkù 8:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 “Kò sí ẹni tó máa tan fìtílà, tó máa wá fi nǹkan bò ó tàbí kó gbé e sábẹ́ ibùsùn, àmọ́ orí ọ̀pá fìtílà ló máa gbé e sí, kí àwọn tó bá wọlé lè rí ìmọ́lẹ̀.+
-