Mátíù 10:31 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 31 Torí náà, ẹ má bẹ̀rù; ẹ níye lórí gan-an ju ọ̀pọ̀ ológoṣẹ́ lọ.+ Lúùkù 12:24 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 24 Ẹ wo àwọn ẹyẹ ìwò: Wọn kì í fúnrúgbìn, wọn kì í sì í kárúgbìn; wọn ò ní abà tàbí ilé ìkẹ́rùsí; síbẹ̀ Ọlọ́run ń bọ́ wọn.+ Ṣé ẹ ò wá níye lórí gan-an ju àwọn ẹyẹ lọ ni?+
24 Ẹ wo àwọn ẹyẹ ìwò: Wọn kì í fúnrúgbìn, wọn kì í sì í kárúgbìn; wọn ò ní abà tàbí ilé ìkẹ́rùsí; síbẹ̀ Ọlọ́run ń bọ́ wọn.+ Ṣé ẹ ò wá níye lórí gan-an ju àwọn ẹyẹ lọ ni?+