Mátíù 10:32, 33 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 32 “Nítorí náà, gbogbo ẹni tó bá fi hàn pé òun mọ̀ mí níwájú àwọn èèyàn,+ èmi náà máa fi hàn pé mo mọ̀ ọ́n níwájú Baba mi tó wà ní ọ̀run.+ 33 Àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá sẹ́ mi níwájú àwọn èèyàn, èmi náà máa sẹ́ ẹ níwájú Baba mi tó wà ní ọ̀run.+
32 “Nítorí náà, gbogbo ẹni tó bá fi hàn pé òun mọ̀ mí níwájú àwọn èèyàn,+ èmi náà máa fi hàn pé mo mọ̀ ọ́n níwájú Baba mi tó wà ní ọ̀run.+ 33 Àmọ́ ẹnikẹ́ni tó bá sẹ́ mi níwájú àwọn èèyàn, èmi náà máa sẹ́ ẹ níwájú Baba mi tó wà ní ọ̀run.+