Éfésù 6:14 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 14 Nítorí náà, ẹ dúró gbọn-in, kí ẹ fi òtítọ́ di inú yín lámùrè,+ kí ẹ sì gbé àwo ìgbàyà òdodo wọ̀,+ 1 Pétérù 1:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Nítorí náà, ẹ múra ọkàn yín sílẹ̀ láti ṣiṣẹ́;+ ẹ máa ronú bó ṣe tọ́ nígbà gbogbo; + ẹ máa retí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a máa fún yín nígbà ìfihàn Jésù Kristi.
13 Nítorí náà, ẹ múra ọkàn yín sílẹ̀ láti ṣiṣẹ́;+ ẹ máa ronú bó ṣe tọ́ nígbà gbogbo; + ẹ máa retí inú rere àìlẹ́tọ̀ọ́sí tí a máa fún yín nígbà ìfihàn Jésù Kristi.