ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 10:34-36
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 34 Ẹ má rò pé mo wá láti mú àlàáfíà wá sí ayé; ṣe ni mo wá láti mú idà wá,+ kì í ṣe àlàáfíà. 35 Torí mo wá láti fa ìpínyà, ọkùnrin sí bàbá rẹ̀, ọmọbìnrin sí ìyá rẹ̀ àti ìyàwó sí ìyá ọkọ rẹ̀.+ 36 Ní tòótọ́, àwọn ará ilé ẹni ló máa jẹ́ ọ̀tá ẹni.

  • Jòhánù 7:41
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 41 Àwọn míì ń sọ pé: “Kristi náà nìyí.”+ Àmọ́ àwọn kan ń sọ pé: “Gálílì kọ́ ni Kristi ti máa jáde wá, àbí ibẹ̀ ni?+

  • Jòhánù 7:43
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 43 Àwọn èrò náà wá pínyà síra wọn nítorí rẹ̀.

  • Jòhánù 9:16
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 16 Àwọn kan lára àwọn Farisí wá bẹ̀rẹ̀ sí í sọ pé: “Ọ̀dọ̀ Ọlọ́run kọ́ ni ọkùnrin yìí ti wá, torí kì í pa Sábáàtì mọ́.”+ Àwọn míì sọ pé: “Báwo ni ọkùnrin tó jẹ́ ẹlẹ́ṣẹ̀ ṣe lè ṣe irú àwọn iṣẹ́ àmì bẹ́ẹ̀?”+ Bí wọ́n ṣe pínyà síra wọn nìyẹn.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́