-
Lúùkù 19:42Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
42 ó ní: “Ká sọ pé ìwọ, àní ìwọ, ti fòye mọ àwọn ohun tó jẹ mọ́ àlàáfíà ní ọjọ́ yìí ni, àmọ́ a ti fi wọ́n pa mọ́ kúrò ní ojú rẹ báyìí.+
-