-
Máàkù 3:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Wọ́n wá ń ṣọ́ ọ lójú méjèèjì, wọ́n ń wò ó bóyá ó máa wo ọkùnrin náà sàn ní Sábáàtì, kí wọ́n lè fẹ̀sùn kàn án.
-
-
Jòhánù 5:15, 16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Ọkùnrin náà lọ, ó sì sọ fún àwọn Júù pé Jésù ló wo òun sàn. 16 Torí èyí, àwọn Júù bẹ̀rẹ̀ sí í ṣe inúnibíni sí Jésù, torí pé ó ń ṣe àwọn nǹkan yìí lọ́jọ́ Sábáàtì.
-