Lúùkù 14:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ta ni ọmọ rẹ̀ tàbí akọ màlúù rẹ̀ máa já sí kànga nínú yín,+ tí kò ní fà á jáde lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní ọjọ́ Sábáàtì?”+
5 Ó wá sọ fún wọn pé: “Ta ni ọmọ rẹ̀ tàbí akọ màlúù rẹ̀ máa já sí kànga nínú yín,+ tí kò ní fà á jáde lẹ́sẹ̀kẹsẹ̀ ní ọjọ́ Sábáàtì?”+