-
Jòhánù 7:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Tí ọkùnrin kan bá dádọ̀dọ́ ní sábáàtì torí kó má bàa rú Òfin Mósè, ṣé ẹ wá ń bínú gidigidi sí mi ni, torí pé mo wo ọkùnrin kan sàn pátápátá ní sábáàtì?+
-