Mátíù 22:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 “A lè fi Ìjọba ọ̀run wé ọba kan tó se àsè ìgbéyàwó+ fún ọmọkùnrin rẹ̀.