ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Mátíù 19:27
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 27 Ni Pétérù bá fèsì pé: “Wò ó! A ti fi ohun gbogbo sílẹ̀, a sì tẹ̀ lé ọ; kí ló máa wá jẹ́ tiwa?”+

  • Lúùkù 9:62
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 62 Jésù sọ fún un pé: “Ẹnikẹ́ni tó bá fi ọwọ́ rẹ̀ lé ohun ìtúlẹ̀, tó wá wo àwọn ohun tó wà lẹ́yìn,+ kò yẹ fún Ìjọba Ọlọ́run.”+

  • Fílípì 3:7, 8
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 7 Síbẹ̀, àwọn ohun tó jẹ́ èrè fún mi ni mo ti kà sí àdánù* nítorí Kristi.+ 8 Yàtọ̀ síyẹn, mo ti ka ohun gbogbo sí àdánù nítorí ìmọ̀ nípa Kristi Jésù Olúwa mi ṣeyebíye ju ohun gbogbo lọ. Nítorí rẹ̀, mo ti gbé ohun gbogbo sọ nù, mo sì kà wọ́n sí ọ̀pọ̀ pàǹtírí,* kí n lè jèrè Kristi,

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́