-
Lúùkù 5:26Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
26 Ẹnu ya gbogbo wọn lẹ́nì kọ̀ọ̀kan, wọ́n sì bẹ̀rẹ̀ sí í yin Ọlọ́run lógo, ẹ̀rù bà wọ́n gan-an, wọ́n ń sọ pé: “A ti rí àwọn nǹkan àgbàyanu lónìí!”
-